jueves, 7 de marzo de 2019

El resultado de la buena actitud.





 

ìÀkùkó f'ogbe lèbèlèbè seyì ;
A dífá fún Opíilíkì
Tí ó fi tiè sílè,
Tí ó maa gbó ti enieleni káyé kiri
Òrúnmìlà ní ó ò bá a tún tiè náà se.
Wón ní kí Opíilíkì ó rúbo,
Kí ó lè baà níyì láyé.
Ó sì rú u.
Ìgbà t' ó rúbo tán,
Wón ní kí ó más tún ti omo elòmíràn se
Ju bí ó ti ń tún ti araa rè se lo.
Ìgbà tí ó se gbogbo è tán,
Tí ó ní òpòlopò omìsìn tán,
Orín awo ní ń ko.
Ó ní kín ní ó bàá mi túnwàa tèmi se?
Òrúnmìlà, ibaà mi, Èrìgì Àlo,
Ni yóò bá mi túnwàa tèmi se. ;
A dífá fún Opíilíkì
Tí ó fi tiè sílè,
Tí ó maa gbó ti enieleni káyé kiri
Òrúnmìlà ní ó ò bá a tún tiè náà se.
Wón ní kí Opíilíkì ó rúbo,
Kí ó lè baà níyì láyé.
Ó sì rú u.
Ìgbà t' ó rúbo tán,
Wón ní kí ó más tún ti omo elòmíràn se
Ju bí ó ti ń tún ti araa rè se lo.
Ìgbà tí ó se gbogbo è tán,
Tí ó ní òpòlopò omìsìn tán,
Orín awo ní ń ko.
Ó ní kín ní ó bàá mi túnwàa tèmi se?
Òrúnmìlà, ibaà mi, Èrìgì Àlo,
Ni yóò bá mi túnwàa tèmi se.


Babalawo IfaKunle Gbawoluyi
Rooster have comb on is head as respect;
cast ifa for Opiiliki
He who leave his own,
But likes to go round the world and be helping others peoples life.
Orunmila will also helping him to resolve his own problem,
Opiiliki was advice to offer sacrifice,
For him to be respected from people of the world.
He complied the sacrifice.
After finishing sacrifice,
He was advice to be helping other people lifes more than his own life.
After follow the instruction giving to him,
After haves many good followers,
He singing of ifa.
What change my attitude to better?
Orunmila ibaa mi, Erigi Alo,
His who will change my attitude to better.

El gallo tiene cresta en su cabeza como respeto;
Opiiliki consulta a Ifa ...
Quien deja lo suyo para ayudar en la vida de otras personas
sera ayudado por Orunmila para resolver su propio problema,
Opiiliki fue aconsejado para ofrecer sacrificio,
para que él sea respetado por las personas del mundo.
Cumplió el sacrificio.
Después de terminar el sacrificio,
fue aconsejado para ayudar a otras personas más que a su propia vida.
Después de seguir las instrucciones que le dan,
Después de tener muchos seguidores buenos ,
El entona una cancion de ifa.
¿Qué cambiará mi actitud para mejorar?
Orunmila iba a mi, Erigi Alo,
El que cambiará mi actitud para mejor.
Dios y ifa orunmila cambiarán nuestras vidas y nuestra actitud para mejorar.
God and ifa orunmila will all change our lifes,& attitude to better, Ase.





















No hay comentarios:

Publicar un comentario